Sáàmù 41:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olùbùkún ni Olúwa, Ọlọ́run Ísírẹ́lìláé àti láéláé.Àmín àti Àmín.

Sáàmù 41

Sáàmù 41:4-13