Sáàmù 40:15-17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

15. Jẹ́ kí àwọn tí ó wí fún mi pé, “Áà! Áá!”ó di ẹni àfọwọ́ rọ́ sẹ́yìn nítorí ìtijú wọn.

16. Jẹ́ kí gbogbo àwọn tí ń wá ọkí ó máa yọ̀kí inú wọn sì máa dùn sí ọ;kí gbogbo àwọn tí ó sì fẹ́ ìgbàlà Rẹkí o máa wí nígbà gbogbo pé,“Gbígbéga ni Olúwa!”

17. Bí ó ṣe ti èmi ni,talákà àti aláìní ni èmi,ṣùgbọ́n Olúwa ń ṣe ìrántí mi.Ìwọ ni olùrànlọ́wọ́ miàti ìgbàlà mi;Má ṣe jẹ́ kí ó pẹ́,ìwọ Ọlọ́run mi.

Sáàmù 40