Sáàmù 40:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ má ṣe,fa àánú Rẹ̀ tí ó rọnúsẹ́yìn kúrò lọ́dọ̀ mi; Olúwajẹ́ kí ìṣeun ìfẹ́ Rẹàti òtítọ́ Rẹkí ó máa pa mí mọ́títí ayérayé.

Sáàmù 40

Sáàmù 40:9-17