Sáàmù 4:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Báwo ni yóò ṣe pẹ́ tó, ẹyin ọmọ ènìyàn, tí ẹ ó ṣe sọ ògo mi di ìtìjú?Báwo ni yóò ṣe pẹ́ tó,tí ẹ̀yin yóò ṣe fẹ́ràn ìtànjẹ́ àti tí ẹ̀yin yóò fi máa wá Ọlọ́run èké?

Sáàmù 4

Sáàmù 4:1-8