Sáàmù 39:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Gbọ́ àdúrà mi, Olúwa,kí o sì fetí sí igbe mi;kí o má ṣe di etí Rẹ sí ẹkún minítorí àlejò ni èmi lọ́dọ̀ Rẹàti àtìpó, bí gbogbo àwọn baba mi ti rí.

Sáàmù 39

Sáàmù 39:3-13