Sáàmù 38:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn tí ó jẹ́ ọ̀tá miláì ní ìdí pàtàkì, wọ́n lágbára púpọ̀,ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni àwọn tí ókórìírá mi lọ́nà òdì.

Sáàmù 38

Sáàmù 38:18-22