Sáàmù 37:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fàsẹ́yìn nínú inúbíbí,kí o sì kọ ìkannú sílẹ̀.Má ṣe ṣe ìkanra,nítorí pé ó gbéni sí búburú pẹ̀lú.

Sáàmù 37

Sáàmù 37:6-12