Sáàmù 37:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbẹ́kẹ̀lé Olúwa,kí o sì máa ṣe rere;torí pé ìwọ yóò gbé ilẹ̀ náà,kí o sì gbádùn ààbò Rẹ̀

Sáàmù 37

Sáàmù 37:1-5