Sáàmù 37:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi ti wà ni èwe,báyìí èmí sì dàgbà;ṣíbẹ̀ èmi kò ì tíi rí kia kọ olódodo ṣílẹ̀,tàbí kí irú ọmọ Rẹ̀máa ṣagbe oúnjẹ.

Sáàmù 37

Sáàmù 37:22-33