Sáàmù 37:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ojú kì yóò tì wọ́n ní àkókò ibi,àti ní ọjọ́ ìyàn, a ó tẹ́ wọn lọ́rùn.

Sáàmù 37

Sáàmù 37:15-23