Sáàmù 37:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ènìyàn búburú fa idà yọ,wọ́n sì tẹ àwọn ọrun wọn,láti sọ talákà àti aláìní kalẹ̀,láti pa àwọn tí ó dúró ṣinṣin.

Sáàmù 37

Sáàmù 37:9-23