Sáàmù 36:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òdodo Rẹ dàbí àwọn òkè Ọlọ́run,àwọn ìdájọ́ Rẹ dàbí ibú ńlá;ìwọ gba ẹranko àti ènìyàn là, Olúwa.

Sáàmù 36

Sáàmù 36:1-12