Sáàmù 35:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jẹ́ kí wọn dà bí ìyàngbò níwájú afẹ́fẹ́,kí ángẹ́lì Olúwakí ó máa lé wọn kiri.

Sáàmù 35

Sáàmù 35:1-11