Sáàmù 35:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fa idà àti ọ̀kọ̀ yọ kí o sì dojúkọ àwọn tí ń lé mi;sọ fún ọkàn mi pé, “Èmi ni ìgbàlà Rẹ.”

Sáàmù 35

Sáàmù 35:1-13