Sáàmù 35:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa, gbógun ti àwọn tí ń gbógun tì mí;kí o sì kọ ojú ìjà sí àwọn tí ó ń bá mi í jà!

Sáàmù 35

Sáàmù 35:1-2