Sáàmù 34:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tọ́ ọ wò kí o sì rí i wí pé Olúwa dára;ẹni ayọ̀ ni ọkùnrin náà tí ó gbẹ́kẹ̀lé ààbò nínú Rẹ̀.

Sáàmù 34

Sáàmù 34:4-10