Sáàmù 34:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi wá Olúwa, ó sì dá mi lóhùn;Ó sì gbà mí kúrò nínú ìbẹ̀rù mi gbogbo.

Sáàmù 34

Sáàmù 34:1-6