Sáàmù 34:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọkàn mí yóò máa ṣògo nínú Olúwa;jẹ́ kí àwọn onírẹ̀lẹ̀ gbọ́ kí inú wọn kí ó sì máa dùn.

Sáàmù 34

Sáàmù 34:1-12