Sáàmù 34:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa sún mọ́ etí ọ̀dọ̀ àwọn oníròbìnújẹ́ ọkàn;ó sì gba irú àwọn tí i ṣe oníròra ọkàn là.

Sáàmù 34

Sáàmù 34:17-22