Sáàmù 34:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ojú Olúwa korò sí àwọn tí ń ṣe búburú;láti ké ìrántí wọn kúrò lórí ilẹ̀.

Sáàmù 34

Sáàmù 34:6-22