Sáàmù 33:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wòó ojú Olúwa wà lára àwọn tí ó bẹ̀rù Rẹ̀,àti lára àwọn tí ó ní ìrètí nínú ìfẹ Rẹ̀ tí ó dúró ṣinṣin,

Sáàmù 33

Sáàmù 33:17-19