Sáàmù 33:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìgbìmọ̀ Olúwa dúró títí ayérayé,àní ìrò inú Rẹ̀ láti ìrandíran ni.

Sáàmù 33

Sáàmù 33:1-20