Sáàmù 33:1-5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ẹyọ̀ nínú Olúwa,ẹ̀yin olódodoìyín si yẹ fún ẹnidídúró ṣinṣin.

2. Ẹyin Olúwa pẹ̀lú dùùrù;ẹ máa fi ohun èlò olókùn mẹ́wàá kọrin sí i.

3. Ẹ kọ orin tuntun sí i;ẹ máa fi ọgbọọgbọ́n lu ohun èlò orin síi,pẹ̀lú ariwo ńlá.

4. Nítorí pé ọ̀rọ̀ Olúwa dúró ṣinṣin,gbogbo iṣẹ́ Rẹ̀ ni à ń ṣenínú òtítọ́.

5. Ó fẹ́ òtítọ́ àti ìdájọ; ilé ayé kún fún ìdúró ṣinṣin àti àánú Olúwa.

Sáàmù 33