Sáàmù 31:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yọ mí jáde kúrò nínú àwọ̀n tí wọ́n dẹ pamọ́ fún mi,nítorí ìwọ ni ìsádi mi.

Sáàmù 31

Sáàmù 31:1-5