Sáàmù 31:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ fẹ́ Olúwa, gbogbo ẹ̀yin ènìyàn Rẹ̀ mímọ́! Olúwa pa olódodo mọ́,ó sì san-án padà fún agbéraga ní ẹ̀kún rẹ́rẹ́.

Sáàmù 31

Sáàmù 31:18-24