Sáàmù 31:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tẹ́ etí Rẹ sí mi,gbà mí kíákíá;jẹ́ àpáta ààbò mi,jẹ́ odi alágbára láti gbà mí.

Sáàmù 31

Sáàmù 31:1-6