Sáàmù 31:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìgbà mi ń bẹ ní ọwọ́ Rẹ;gbà mí kúrò ní ọwọ́ àwọn ọ̀tá miàti àwọn onínúnibíni.

Sáàmù 31

Sáàmù 31:11-24