Sáàmù 30:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Èrè kí ni ó wà nínú ikú ìparun mi,nínú lílọ sí ihò mi?Eruku yóò a yìn ọ́ bí?Ǹjẹ́ yóò sọ nípa òdodo Rẹ?

Sáàmù 30

Sáàmù 30:1-12