Sáàmù 30:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nípa ojúrere Rẹ̀, Olúwa,ìwọ ti gbé mi kalẹ̀ bí òkè tí ó ní agbára;ìwọ pa ojú Rẹ mọ́,àyà sì fò mí.

Sáàmù 30

Sáàmù 30:6-8