Sáàmù 30:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kọ orin ìyìn sí Olúwa, ẹ̀yin olódodo;kí ẹ sì fi ọpẹ́ fún orúkọ Rẹ̀ mímọ́.

Sáàmù 30

Sáàmù 30:1-12