nítorí ìdí èyí ni kí ọkàn mi máa yìn ọ́, kí ó má sì ṣe dákẹ́.Ìwọ Olúwa Ọlọ́run mi, èmi yóò máa fi ọpẹ́ fún ọ títí láé.