Sáàmù 27:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa ni ìmọ́lẹ̀ mi àti ìgbàlà mi;ta ni èmi yóò bẹ̀rù? Olúwa ni ibi olódì ẹ̀mí mi,ta ni ẹni tí èmi yóò bẹ̀rù?

Sáàmù 27

Sáàmù 27:1-5