Sáàmù 26:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmí ó wẹ ọwọ́ mi ní àìlẹ́ṣẹ̀,bẹ́ẹ̀ ni èmi yóò sì yí pẹpẹ Rẹ ká Olúwa

Sáàmù 26

Sáàmù 26:1-12