Sáàmù 25:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jẹ́ kí òtítọ́ inú àti ìdúró ṣinṣin kí ó pa mí mọ́;nítorí pé mo dúró tì ọ́.

Sáàmù 25

Sáàmù 25:16-22