Sáàmù 25:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọlọ́run, èmi gbẹ́kẹ̀lé ọ;Má ṣe jẹ́ kí ojú ó tì míMá ṣe jẹ́ kí àwọn ọ̀ta mi ó yọ̀ mí.

Sáàmù 25

Sáàmù 25:1-9