Sáàmù 24:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbé orí yín sókè, áà! Ẹ̀yin ọ̀nà;Kí a sì gbé yín sókè, ẹ̀yin ìlẹ̀kùn ayérayé,Kí ọba ògo le è wọlé wá.

Sáàmù 24

Sáàmù 24:1-10