Sáàmù 24:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ gbé orí yín sókè, Áà! Ẹ̀yin ọ̀nà;Kí á sì gbe yín sókè, áà! Ẹyin ilẹ̀kùn ayérayé!Kí ọba ògo le è wọlé.

Sáàmù 24

Sáàmù 24:4-10