Sáàmù 24:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹni tí ó ní ọwọ́ mímọ́ àti àyà funfun,ẹni tí kò gbé ọkàn Rẹ̀ sókè sí asántí kò sì búra èké.

Sáàmù 24

Sáàmù 24:1-7