Sáàmù 22:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n kòkòrò ní mo jẹ́ kì í sì í ṣe ènìyàn;mo di ẹlẹ́gàn àwọn ènìyàn ẹlẹ́yà àwọ́n ènìyàn

Sáàmù 22

Sáàmù 22:1-9