Sáàmù 22:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ̀yin tí ẹ bẹ̀rù Olúwa, ẹyìn-ín!Gbogbo ẹ̀yin ìran Jákọ́bù, ẹ fi ògo fún-un!ẹ dìde fún-un tẹ̀rù tẹ̀rù, ẹ̀yin irú ọmọ Ísírẹ́lì!

Sáàmù 22

Sáàmù 22:20-27