Sáàmù 22:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo lè ka gbogbo àwọn egungun mi;àwọn tìkára wọn ń wò, wọ́n dójú lé mi.

Sáàmù 22

Sáàmù 22:12-20