Sáàmù 22:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Agbára mí ti gbẹ bí àpáàdì,ahọ́n mí sì ti lẹ̀ mọ́ párí ẹ̀rẹ̀kẹ́ ẹ mi;ìwọ ti tẹ́ mi sínú eruku ikú.

Sáàmù 22

Sáàmù 22:11-25