Sáàmù 21:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Áà! Olúwa, Ọba yóò yọ̀ nínú agbára Rẹ,àti ní ìgbàlà Rẹ, yóò ti yọ̀ pẹ́ tó!

Sáàmù 21

Sáàmù 21:1-11