Sáàmù 20:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwa yóò hó fún ayọ̀ nígbà tí o bá di aṣẹ́gunàwa yóò gbé àsíá wa sókè ní orúkọ Ọlọ́run wa.Kí Ọlọ́run kí ó mú gbogbo ìbéèrè Rẹ̀ ṣẹ.

Sáàmù 20

Sáàmù 20:3-9