Sáàmù 18:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó pín àwọn ọ̀run, Ó sì jáde wá;àwọsánmọ̀ dúdú sì wà ní abẹ́ ẹsẹ̀ Rẹ̀.

Sáàmù 18

Sáàmù 18:6-13