Sáàmù 18:50 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó fún Ọba Rẹ̀ ni ìṣẹ́gun ńlá;ó fi ìkáànú àìṣẹ̀tàn fún ẹni-àmì-òróró Rẹ̀,fún Dáfídì àti ìran Rẹ̀ títí láé.

Sáàmù 18

Sáàmù 18:41-50