Sáàmù 18:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìrora ikú yí mi kà,àti ìsàn omi àwọn ènìyàn búbúrú dẹ́rùbà mí.

Sáàmù 18

Sáàmù 18:1-7