Sáàmù 18:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó ṣe ẹsẹ̀ mi gẹ́gẹ́ bi ẹsẹ̀ àgbọ̀nrín;ó jẹ́ ki n lè dúró lórí ibi gíga.

Sáàmù 18

Sáàmù 18:31-39