Sáàmù 18:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sọ̀kalẹ̀ láti ibi gíga ó sì dì mí mú;Ó fà mí jáde láti inú omi jínjìn.

Sáàmù 18

Sáàmù 18:10-25