Sáàmù 18:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó ta àwọn ọfà Rẹ̀, ó sì tú àwọn ọ̀ta náà ká,ọfà mọ̀nàmọ́ná ńlá sì dà wọ́n rú.

Sáàmù 18

Sáàmù 18:4-22